Awon aworan eto Igbeyawo laarin Oluyemi Olanike Bukola ati Adeleye Olusesan
Igbeyawo je ohun iwuri ati idunnu fun gbogbo obinrin to ba fara bale gba eko awon obi, ki o to sa to okunrin lo....Ojo pataki ni ojo igbeyawo maa n je fun awa obinrin, koda, ojo idunu tun ni fun awon okunrin, paapaa julo awon obi oko ati ti iyawo.
wonyi ni awon aworan eto igbeyawo okan lara awon osise ile-ise Royal Fm 95.1 Ilorin (Oluyemi Olanike Bukola)
haa..emi ni mo fe arewa to rewa to eyi, ni ohun ti o wa lokan oko-iyawo to fi n woju aya re
Mo fe ohun ti mo le gbe (I marry who I can carry). (awada)
Eyin abelejayan, e lo wabi joko si nitori Adeleye Olusesan ti laya tie.
Eyin oloju-komu-kolo, e lo sempe, nitori Oluyemi Olanike Bukola ti loko tie
Awa mejeeji ti di okan lati oni lo..........ajosepo wa yio larinrin loruko JESU. AMIN
No comments:
Post a Comment