ASO ANKARA
Aso ankara ti d'aye ojo ti pe, bee ona ti jin pelu. Nigba kan ri, leyin ki a fi aso ankara ran ewu s'orun, ko tun si ohun meji ti a tun n fi ankara se mo, Sugbon bi ojo de n gori ojo,ni imo tun gori imo,bee ni awon ohun otun tun n d'aye, lo difa fun aso ankara to wa di ohun ti o gbajumo julo ninu gbogbo awon oniruuru aso towa nile yooba. Orisiri awon eso ara(accessories)ni won tun ti n fi aso ankara se bayi, ko fe e si eso ara kan ti won ko le fi aso ankara se bayi nile yooba, awon aloku aso (pieces) wa di ohun ti awon ransoranso tun n naani, ti won n ta fun awon eeyan lati fi se eso ara bii:egba orun, oruka owo, bata, baagi, beliti, tayi (tie) ati bee bee lo. E wo aworan awon nnkan wonyi
 |
Oniruuru Baagi ti a se pelu Aso Ankara |
 |
Awon Bata, Egba owo ati Oruka owo ti a fi Ankara se |
 |
Beliti alawo Ankara |
 |
Baagi ti a se pelu Ankara alawo yelo ati bulu |
 |
Ewo Egba orun ti a sinpo pelu Ankara |
 |
Bata giga ti a se pelu Ankara |
 |
Eekannna igbalode ti a se pelu awo ankara |
 |
Tayi (tie) ti a fi aso ankara se |
 |
Eso ti a fi n se irun loge |
 |
Bata ti a fi Ankara da lara |
 |
Pilo ori Aga(Throw Pilow) ti a fi Ankara se
Ankara ti gbayi, o gbeye, ni ile kaaro-o-jiire, ati ni gbogbo orile ede agbaye patapata
|