Wednesday, 11 September 2013
Gbigbe asa ile Yoruba ga je nnkan ti o je awon eniyan kan logun lagbole ise sorosoro, lojuna ati ri wipe a se adapada awon ohun ti o ti sonu ninu asa ile wa, paapaa julo nipase olaju. Bi a ba woo daradara, a o ri wipe, ko si eni ti o wo aso ile Yoruba ti ko ni se regi lara re. Wonyi ni aworan awon omo Yoruba atata, ti won n fi amura ati isesi won gbe asa ile Yoruba Laruge. A ko awon aworan yi jo nibi ayeye IGBELARUGE ASA ti okan lara awon sorosoro 'Bebe Musiliu' ati City People Media Group se agbateru re , fun ifami-eye-dani-lola ati sise agbajade awo orin 'Ogodo Egba' ni ojo aiku, ojo kejo, osu kesan, odun 2013, ni daktad event centre, ibara abeokuta.
Subscribe to:
Posts (Atom)